Word-by-wordSyncAudioBible
Gbiyanju Davar fun ọfẹGen.8.1
Jọwọ ronu lati pin ẹsẹ Bibeli kan loni pẹlu ijọ rẹ, awọn ọrẹ, ati ẹbi rẹ. O ṣeun, OLORUN a bukun fun ọ!
YBCV
ỌLỌRUN si ranti Noa, ati ohun alãye gbogbo, ati gbogbo ẹran-ọ̀sin ti o wà pẹlu rẹ̀ ninu ọkọ̀: Ọlọrun si mu afẹfẹ kọja lori ilẹ, omi na si fà.
The Ark Rests on Ararat
The Flood Subsides
Noah Sends a Raven and a Dove
Exiting the Ark
Noah Builds an Altar

Awọn Itọkasi Agbelebu
Ko si awọn itọkasi agbelebu fun ẹsẹ yii.