דָּבָר·DavarWord-by-wordSyncAudioBibleHebrewOldTestamentGreekNewTestamentTransliteration&Definitions Gbiyanju Davar fun ọfẹ →
Gẹnẹsisi 30:18YBCVLea si wipe, Ọlọrun san ọ̀ya mi fun mi, nitori ti mo fi iranṣẹbinrin mi fun ọkọ mi; o si pè orukọ rẹ̀ ni Issakari. Gẹnẹsisi 30 Gẹnẹsisi 30 Gẹnẹsisi 30:17-21 Gẹnẹsisi 30:17-21 Gẹnẹsisi 30:1-24 Gẹnẹsisi 30:1-24 Pin Issachar, Zebulun, and DinahThe Sons of Jacob
Gẹnẹsisi 30:20YBCVLea si wipe, Ọlọrun ti fun mi li ẹ̀bun rere; nigbayi li ọkọ mi yio tó ma bá mi gbé, nitori ti mo bí ọmọkunrin mẹfa fun u: o si pè orukọ rẹ̀ ni Sebuluni. Gẹnẹsisi 30 Gẹnẹsisi 30 Gẹnẹsisi 30:17-21 Gẹnẹsisi 30:17-21 Gẹnẹsisi 30:1-24 Gẹnẹsisi 30:1-24 Pin Issachar, Zebulun, and DinahThe Sons of Jacob